Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 6:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Eyi li ofin ti Nasiri ti o ṣe ileri, ati ti ọrẹ-ẹbọ rẹ̀ si OLUWA fun ìyasapakan rẹ̀ li àika eyiti ọwọ́ on le tẹ̀: gẹgẹ bi ileri ti o ṣe, bẹ̃ni ki o ṣe nipa ofin ìyasapakan rẹ̀.

Ka pipe ipin Num 6

Wo Num 6:21 ni o tọ