Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 34:25-29 Yorùbá Bibeli (YCE)

25. Ati olori ẹ̀ya awọn ọmọ Sebuluni, Elisafani ọmọ Parnaki.

26. Ati olori ẹ̀ya awọn ọmọ Issakari, Paltieli ọmọ Assani.

27. Ati olori ẹ̀ya awọn ọmọ Aṣeri, Ahihudu ọmọ Ṣelomi.

28. Ati olori ẹ̀ya awọn ọmọ Naftali, Pedaheli ọmọ Ammihudu.

29. Awọn wọnyi li ẹniti OLUWA paṣẹ fun lati pín iní na fun awọn ọmọ Israeli ni ilẹ Kenaani.

Ka pipe ipin Num 34