Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 33:12-27 Yorùbá Bibeli (YCE)

12. Nwọn si ṣí kuro ni aginjù Sini, nwọn si dó si Dofka.

13. Nwọn si ṣí kuro ni Dofka, nwọn si dó si Aluṣi.

14. Nwọn si ṣí kuro ni Aluṣi, nwọn si dó si Refidimu, nibiti omi kò gbé sí fun awọn enia na lati mu.

15. Nwọn si ṣí kuro ni Refidimu, nwọn si dó si aginjù Sinai.

16. Nwọn si ṣí kuro ni aginjù Sinai, nwọn si dó si Kibrotu-hattaafa.

17. Nwọn si ṣí kuro ni Kibrotu-hattaafa, nwọn si dó si Haserotu.

18. Nwọn si ṣí kuro ni Haserotu, nwọn si dó si Ritma.

19. Nwọn si ṣí kuro ni Ritma, nwọn si dó si Rimmon-peresi.

20. Nwọn si ṣí kuro ni Rimmon-peresi, nwọn si dó si Libna.

21. Nwọn si ṣí kuro ni Libna, nwọn si dó si Rissa.

22. Nwọn si ṣí kuro ni Rissa, nwọn si dó si Kehelata.

23. Nwọn si ṣí kuro ni Kehelata, nwọn si dó si òke Ṣeferi.

24. Nwọn si ṣí kuro ni òke Ṣeferi, nwọn si dó si Harada.

25. Nwọn si ṣí kuro ni Harada, nwọn si dó si Makhelotu.

26. Nwọn si ṣí kuro ni Makhelotu, nwọn si dó si Tahati.

27. Nwọn si ṣí kuro ni Tahati, nwọn si dó si Tera.

Ka pipe ipin Num 33