Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 32:40-42 Yorùbá Bibeli (YCE)

40. Mose si fi Gileadi fun Makiri ọmọ Manase; o si joko ninu rẹ̀.

41. Jairi ọmọ Manasse, si lọ, o si gbà awọn ilu wọn, o si sọ wọn ni Haffotu-jairi.

42. Noba si lọ, o si gbà Kenati, ati awọn ileto rẹ̀, o si sọ ọ ni Noba, nipa orukọ ara rẹ̀.

Ka pipe ipin Num 32