Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 32:36-38 Yorùbá Bibeli (YCE)

36. Ati Beti-nimra, ati Beti-harani, ilu olodi, ati agbo fun agutan.

37. Awọn ọmọ Reubeni si kọ́ Heṣboni, ati Eleale, ati Kiriataimu.

38. Ati Nebo, ati Baali-meoni, (nwọn pàrọ orukọ wọn,) ati Sibma: nwọn si sọ ilu ti nwọn kọ́ li orukọ miran.

Ka pipe ipin Num 32