Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 32:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ibinu OLUWA si rú si Israeli, o si mu wọn rìn kiri li aginjù li ogoji ọdún, titi gbogbo iran na, ti o ṣe buburu li oju OLUWA fi run.

Ka pipe ipin Num 32

Wo Num 32:13 ni o tọ