Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 31:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si pa awọn ọba Midiani, pẹlu awọn iyokù ti a pa; eyinì ni Efi, ati Rekemu, ati Suru, ati Huri, ati Reba, ọba Midiani marun: Balaamu ọmọ Beoru ni nwọn si fi idà pa.

Ka pipe ipin Num 31

Wo Num 31:8 ni o tọ