Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 30:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ti baba rẹ̀ si gbọ́ ẹjẹ́ rẹ̀, ati ìde rẹ̀ ti o fi dè ara rẹ̀, ti baba rẹ̀ ba si pa ẹnu rẹ̀ mọ́ si i; njẹ ki gbogbo ẹjẹ́ rẹ̀ ki o duro, ati gbogbo ìde ti o fi dè ara rẹ̀ yio si duro.

Ka pipe ipin Num 30

Wo Num 30:4 ni o tọ