Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 30:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi ọkunrin kan ba jẹ́ ẹjẹ́ fun OLUWA, tabi ti o ba bura lati fi dè ara rẹ̀ ni ìde, ki on ki o máṣe bà ọ̀rọ rẹ̀ jẹ; ki on ki o ṣe gẹgẹ bi gbogbo eyiti o ti ẹnu rẹ̀ jade.

Ka pipe ipin Num 30

Wo Num 30:2 ni o tọ