Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 3:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Apoti, ati tabeli, ati ọpá-fitila, ati pẹpẹ wọnni, ati ohun-èlo ibi-mimọ́, eyiti nwọn fi nṣe iṣẹ alufa, ati aṣọ-tita, ati gbogbo ohun-èlo iṣẹ-ìsin rẹ̀, ni yio jẹ́ ohun itọju wọn.

Ka pipe ipin Num 3

Wo Num 3:31 ni o tọ