Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 27:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi baba rẹ̀ kò ba si lí arakunrin, njẹ ki ẹnyin ki o fi ilẹ-iní rẹ̀ fun ibatan rẹ̀, ti o sunmọ ọ ni idile rẹ̀, on ni ki o jogún rẹ̀: yio si jasi ìlana idajọ fun awọn ọmọ Israeli, gẹgẹ bi OLUWA ti paṣẹ fun Mose.

Ka pipe ipin Num 27

Wo Num 27:11 ni o tọ