Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 26:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati awọn ọmọ Eliabu; Nemueli, ati Datani, ati Abiramu. Eyi ni Datani ati Abiramu na, ti nwọn lí okiki ninu ijọ, ti nwọn bá Mose ati Aaroni jà ninu ẹgbẹ Kora, nigbati nwọn bá OLUWA jà.

Ka pipe ipin Num 26

Wo Num 26:9 ni o tọ