Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 25:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si tọ̀ ọkunrin Israeli na lọ ninu agọ́, o si fi gún awọn mejeji li agunyọ, ọkunrin Israeli na, ati obinrin na ni inu rẹ̀. Àrun si da lãrin awọn ọmọ Israeli.

Ka pipe ipin Num 25

Wo Num 25:8 ni o tọ