Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 25:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoriti nwọn fi ẹ̀tan wọn yọ nyin lẹnu, eyiti nwọn tàn nyin niti ọ̀ran Peori, ati niti ọ̀ran Kosbi, ọmọ ijoye Midiani kan, arabinrin wọn, ẹniti a pa li ọjọ́ àrun nì niti ọ̀ran Peori.

Ka pipe ipin Num 25

Wo Num 25:18 ni o tọ