Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 24:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi ri i, ṣugbọn ki iṣe nisisiyi: emi si wò o, ṣugbọn kò sunmọtosi: irawọ kan yio ti inu Jakobu jade wá, ọpa-alade kan yio si ti inu Israeli dide, yio si kọlù awọn igun Moabu, yio si ṣẹ́ gbogbo awọn ọmọ irọkẹ̀kẹ.

Ka pipe ipin Num 24

Wo Num 24:17 ni o tọ