Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 23:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si bẹ̀rẹsi owe rẹ̀, o si wipe, Balaki ọba Moabu mú mi lati Aramu wá, lati òke-nla ìla-õrún wá, wipe, Wá, fi Jakobu bú fun mi, si wá, ki o fi Israeli ré.

Ka pipe ipin Num 23

Wo Num 23:7 ni o tọ