Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 22:34 Yorùbá Bibeli (YCE)

Balaamu si wi fun angeli OLUWA pe, Emi ti ṣẹ̀; nitori emi kò mọ̀ pe iwọ duro dè mi li ọ̀na; njẹ bi kò ba ṣe didùn inu rẹ, emi o pada.

Ka pipe ipin Num 22

Wo Num 22:34 ni o tọ