Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 22:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kẹtẹkẹtẹ na si ri angeli OLUWA duro loju ọ̀na, idà rẹ̀ fifàyọ si wà li ọwọ́ rẹ̀: kẹtẹkẹtẹ na si yà kuro loju ọ̀na, o si wọ̀ inu igbẹ́: Balaamu si lù kẹtẹkẹtẹ na, lati darí rẹ̀ soju ọ̀na.

Ka pipe ipin Num 22

Wo Num 22:23 ni o tọ