Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 22:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Balaamu si dahùn o si wi fun awọn iranṣẹ Balaki pe, Balaki iba fẹ́ fun mi ni ile rẹ̀ ti o kún fun fadaká ati wurà, emi kò le rekọja ọ̀rọ OLUWA Ọlọrun mi, lati ṣe ohun kekere tabi nla.

Ka pipe ipin Num 22

Wo Num 22:18 ni o tọ