Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 22:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. AWỌN ọmọ Israeli si ṣí, nwọn si dó si pẹtẹlẹ̀ Moabu li apa keji Jordani ti o kọjusi Jeriko.

2. Balaki ọmọ Sippori si ri gbogbo eyiti Israeli ti ṣe si awọn ọmọ Amori.

Ka pipe ipin Num 22