Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 21:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina li awọn enia na ṣe tọ̀ Mose wá, nwọn si wipe, Awa ti ṣẹ̀, nitoriti awa ti bá OLUWA ati iwọ sọ̀; gbadura si OLUWA ki o mú ejò wọnyi kuro lọdọ wa. Mose si gbadura fun awọn enia na.

Ka pipe ipin Num 21

Wo Num 21:7 ni o tọ