Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 21:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si rìn lati òke Hori lọ li ọ̀na Okun Pupa, lati yi ilẹ Edomu ká: sũru si tán awọn enia na pupọ̀pupọ nitori ọ̀na na.

Ka pipe ipin Num 21

Wo Num 21:4 ni o tọ