Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 21:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lati ibẹ̀ lọ nwọn ṣí, nwọn si dó si ìha keji Arnoni, ti mbẹ li aginjù, ti o ti àgbegbe awọn ọmọ Amori wá: nitoripe Arnoni ni ipinlẹ Moabu, lãrin Moabu ati awọn Amori.

Ka pipe ipin Num 21

Wo Num 21:13 ni o tọ