Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 20:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mú ọpá nì, ki o si pe ijọ awọn enia jọ, iwọ, ati Aaroni arakunrin rẹ, ki ẹ sọ̀rọ si apata nì li oju wọn, yio si tú omi rẹ̀ jade; iwọ o si mú omi lati inu apata na jade fun wọn wá: iwọ o si fi fun ijọ ati fun ẹran wọn mu.

Ka pipe ipin Num 20

Wo Num 20:8 ni o tọ