Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 20:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA si sọ fun Mose ati fun Aaroni pe, Nitoriti ẹnyin kò gbà mi gbọ́, lati yà mi simimọ́ loju awọn ọmọ Israeli, nitorina ẹnyin ki yio mú ijọ awọn enia yi lọ si ilẹ na ti mo fi fun wọn.

Ka pipe ipin Num 20

Wo Num 20:12 ni o tọ