Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 2:34 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọmọ Israeli si ṣe gẹgẹ bi gbogbo eyiti OLUWA paṣẹ fun Mose: bẹ̃ni nwọn si dó pẹlu ọpagun wọn, bẹ̃ni nwọn si nṣí, olukuluku nipa idile wọn, gẹgẹ bi ile baba wọn.

Ka pipe ipin Num 2

Wo Num 2:34 ni o tọ