Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 19:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki ọkunrin kan ti o mọ́ ki o si kó ẽru ẹgbọrọ abomalu na, ki o si kó o jọ si ibi kan ti o mọ́ lẹhin ibudó, ki a si pa a mọ́ fun ijọ awọn ọmọ Israeli fun omi ìyasapakan: ẹbọ ẹ̀ṣẹ ni.

Ka pipe ipin Num 19

Wo Num 19:9 ni o tọ