Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 19:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Eyi ni ìlana ofin, ti OLUWA palaṣẹ, wipe, Sọ fun awọn ọmọ Israeli, ki nwọn ki o mú ẹgbọrọ abomalu pupa kan tọ̀ ọ wá, alailabawọ́n, ati alailabùku, ati lara eyiti a kò ti dì àjaga mọ́:

Ka pipe ipin Num 19

Wo Num 19:2 ni o tọ