Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 19:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki ẹnikan ti o mọ́ ki o si mú hissopu, ki o si tẹ̀ ẹ bọ̀ inu omi na, ki o si fi i wọ́n agọ́ na, ati ohun-èlo gbogbo, ati sara awọn enia ti o wá nibẹ̀, ati sara ẹniti o fọwọkàn egungun kan, tabi ẹnikan ti a pa, tabi ẹnikan ti o kú, tabi isà-okú:

Ka pipe ipin Num 19

Wo Num 19:18 ni o tọ