Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 18:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA si sọ fun Aaroni pe, Kiyesi i, emi si ti fi itọju ẹbọ igbesọsoke mi fun ọ pẹlu, ani gbogbo ohun mimọ́ awọn ọmọ Israeli, iwọ li emi fi wọn fun ni ipín, ati fun awọn ọmọ rẹ, bi ipín lailai.

Ka pipe ipin Num 18

Wo Num 18:8 ni o tọ