Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 18:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina ki iwọ ki o wi fun wọn pe, Nigbati ẹnyin ba fi eyiti o dara ninu rẹ̀ ṣe ẹbọ igbesọsoke, nigbana ni ki a kà a fun awọn ọmọ Lefi bi ọkà ilẹ-ipakà, ati bi ibisi ibi-ifunti.

Ka pipe ipin Num 18

Wo Num 18:30 ni o tọ