Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 16:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ohun kekere ha ni li oju nyin, ti Ọlọrun Israeli yà nyin kuro ninu ijọ Israeli, lati mú nyin sunmọ ọdọ ara rẹ̀ lati ma ṣe iṣẹ-ìsin agọ́ OLUWA, ati lati ma duro niwaju ijọ lati ma ṣe iranṣẹ fun wọn;

Ka pipe ipin Num 16

Wo Num 16:9 ni o tọ