Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 14:40 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si dide ni kùtukutu owurọ̀, nwọn si gùn ori òke nì lọ, wipe, Kiyesi i, awa niyi, awa o si gòke lọ si ibiti OLUWA ti ṣe ileri: nitoripe awa ti ṣẹ̀.

Ka pipe ipin Num 14

Wo Num 14:40 ni o tọ