Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 14:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o ti mu sũru pẹ to fun ijọ enia buburu yi ti nkùn si mi? Emi ti gbọ́ kikùn awọn ọmọ Israeli, ti nwọn kùn si mi.

Ka pipe ipin Num 14

Wo Num 14:27 ni o tọ