Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 13:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati bi ilẹ na ti ri, bi ẹlẹtu ni tabi bi aṣalẹ̀, bi igi ba mbẹ ninu rẹ̀, tabi kò sí. Ki ẹnyin ki o si mu ọkàn le, ki ẹnyin si mú ninu eso ilẹ na wá. Njẹ ìgba na jẹ́ akokò pipọn akọ́so àjara.

Ka pipe ipin Num 13

Wo Num 13:20 ni o tọ