Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 13:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki ẹnyin si wò ilẹ na, bi o ti ri; ati awọn enia ti ngbé inu rẹ̀, bi nwọn ṣe alagbara tabi alailagbara, bi diẹ ni nwọn, tabi pupọ̀;

Ka pipe ipin Num 13

Wo Num 13:18 ni o tọ