Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 1:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ti awọn ọmọ Simeoni, iran wọn, nipa idile wọn, nipa ile baba wọn, awọn ti a kà ninu wọn, gẹgẹ bi iye orukọ, nipa ori wọn, gbogbo ọkunrin lati ẹni ogún ọdún lọ ati jù bẹ̃ lọ, gbogbo awọn ti o le jade lọ si ogun;

Ka pipe ipin Num 1

Wo Num 1:22 ni o tọ