Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 1:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati awọn ọmọ Reubeni, akọ́bi Israeli, iran wọn, nipa idile wọn, nipa ile baba wọn, gẹgẹ bi iye orukọ, nipa ori wọn, gbogbo ọkunrin lati ẹni ogún ọdún lọ ati jù bẹ̃ lọ, gbogbo awọn ti o le jade lọ si ogun;

Ka pipe ipin Num 1

Wo Num 1:20 ni o tọ