Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Neh 9:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ si jẹri gbè wọn ki iwọ ki o le tun mu wọn wá sinu ofin rẹ, ṣugbọn nwọn hu ìwa igberaga, nwọn kò si fi eti si ofin rẹ, nwọn si ṣẹ̀ si idajọ rẹ (eyiti bi enia ba ṣe on o yè ninu wọn), nwọn si gún èjika, nwọn mu ọrùn wọn le, nwọn kò si fẹ igbọ́.

Ka pipe ipin Neh 9

Wo Neh 9:29 ni o tọ