Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Neh 9:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si gbà ilu alagbara, ati ilẹ ọlọra, nwọn si gbà ilẹ ti o kún fun ohun rere, kanga, ọgba-ajara, ọgba-olifi, ati igi eleso, li ọ̀pọlọpọ: bẹ̃ni nwọ́n jẹ, nwọn si yo, nwọ́n sanra, nwọn si ni inu-didùn ninu ore rẹ nla.

Ka pipe ipin Neh 9

Wo Neh 9:25 ni o tọ