Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Neh 9:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn iwọ, ninu ọ̀pọlọpọ ãnu rẹ, kò kọ̀ wọn silẹ li aginju, ọwọ̀n kũkũ kò kuro lọdọ wọn lojojumọ lati ṣe amọna wọn, bẹ̃ si li ọwọ̀n iná lati fun wọn ni imọlẹ li oru li ọ̀na ti nwọn iba rìn.

Ka pipe ipin Neh 9

Wo Neh 9:19 ni o tọ