Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Neh 8:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni awọn enia na jade lọ, nwọn si mu wọn wá, nwọn pa agọ fun ara wọn, olukuluku lori orule ile rẹ̀, ati li àgbala wọn, ati li àgbala ile Ọlọrun, ati ni ita ẹnu-bode omi, ati ni ita ẹnu-bode Efraimu.

Ka pipe ipin Neh 8

Wo Neh 8:16 ni o tọ