Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Neh 7:41-54 Yorùbá Bibeli (YCE)

41. Awọn ọmọ Paṣuri, ẹgbẹfa o le mẹtadiladọta.

42. Awọn ọmọ Harimu ẹgbẹrun o le mẹtadilogun.

43. Awọn ọmọ Lefi: awọn ọmọ Jeṣua, ti Kadmieli, ninu ọmọ Hodafa, mẹrinlelãdọrin.

44. Awọn akọrin: awọn ọmọ Asafu, mejidilãdọjọ.

45. Awọn oludena: awọn ọmọ Ṣallumu, awọn ọmọ Ateri, awọn ọmọ Talmoni, awọn ọmọ Akkubu, awọn ọmọ Hatita, awọn ọmọ Ṣobai, mejidilogoje.

46. Awọn ọmọ Netinimu: awọn ọmọ Siha, awọn ọmọ Haṣufa, awọn ọmọ Tabbaoti,

47. Awọn ọmọ Kerosi, awọn ọmọ Sia, awọn ọmọ Padoni,

48. Awọn ọmọ Lebana, awọn ọmọ Hagaba, awọn ọmọ Salmai,

49. Awọn ọmọ Hanani, awọn ọmọ Giddeli, awọn ọmọ Gahari,

50. Awọn ọmọ Reaiah, awọn ọmọ Resini, awọn ọmọ Nekoda,

51. Awọn ọmọ Gassamu, awọn ọmọ Ussa, awọn ọmọ Fasea,

52. Awọn ọmọ Besai, awọn ọmọ Meunimu, awọn ọmọ Nefiṣesimu,

53. Awọn ọmọ Bakbuku, awọn ọmọ Hakufa, awọn ọmọ Harhuri,

54. Awọn ọmọ Basliti, awọn ọmọ Mehida, awọn ọmọ Harsa,

Ka pipe ipin Neh 7