Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Neh 6:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati gbogbo awọn ọta wa gbọ́, gbogbo awọn keferi àgbegbe wa si bẹ̀ru, nwọn si rẹ̀wẹsi pupọ li oju ara wọn, nitori nwọn woye pe, lati ọwọ Ọlọrun wá li a ti ṣe iṣẹ wọnyi.

Ka pipe ipin Neh 6

Wo Neh 6:16 ni o tọ