Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Neh 6:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mo si wá si ile Ṣemaiah ọmọ Delaiah ọmọ Mehetabeeli, ti a há mọ, o si wipe, Jẹ ki a pejọ ni ile Ọlọrun ni inu tempili ki a si tì ilẹkùn tempili; nitori nwọn o wá lati pa ọ; nitõtọ, li oru ni nwọn o wá lati pa ọ.

Ka pipe ipin Neh 6

Wo Neh 6:10 ni o tọ