Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Neh 3:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lọwọkọwọ wọn ni Meremoti ọmọ Urijah, ọmọ Kosi, tun ṣe. Ati lọwọkọwọ wọn ni Meṣullamu, ọmọ Berekiah, ọmọ Meṣesabeli tun ṣe. Ati lọwọkọwọ wọn ni Sadoku, ọmọ Baana tun ṣe.

Ka pipe ipin Neh 3

Wo Neh 3:4 ni o tọ