Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Neh 3:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Palali ọmọ Usai li ọkánkán igun odi, ati ile-iṣọ ti o yọ sode lati ile giga ti ọba wá ti o wà lẹba ile tubu. Lẹhin rẹ̀ ni Padaiah ọmọ Paroṣi.

Ka pipe ipin Neh 3

Wo Neh 3:25 ni o tọ