Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Neh 3:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lẹhin wọn ni Benjamini ati Haṣubu tun ṣe li ọkánkán ile wọn. Lẹhin wọn ni Asariah ọmọ Maasiah ọmọ Ananiah tun ṣe lẹba ile rẹ̀.

Ka pipe ipin Neh 3

Wo Neh 3:23 ni o tọ