Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Neh 3:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣallumu, ọmọ Kol-hose, ijòye apakan Mispa si tun ẹnu-bode orisun ṣe; o kọ́ ọ, o si bò o, o si gbe ilẹkùn rẹ̀ ro, àgadágodo rẹ̀, ati itìkun rẹ̀ ati odi adagun Ṣiloa li ẹ̀ba ọgba ọba, ati titi de atẹ̀gun ti o sọkalẹ lati ile Dafidi lọ.

Ka pipe ipin Neh 3

Wo Neh 3:15 ni o tọ