Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Neh 3:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Hanuni pẹlu awọn ará Sanoa si tun ẹnu-bode afonifoji ṣe; nwọn kọ́ ọ, nwọn si gbe ilẹkùn rẹ̀ ro, àgadágodo rẹ̀ ati itikùn rẹ̀, ati ẹgbẹrun igbọnwọ odi titi de ẹnu-bode ãtàn.

Ka pipe ipin Neh 3

Wo Neh 3:13 ni o tọ